Dami Drizzy – Ifa Wa Kayejo

Dami Drizzy - Ifa Wa Kayejo

Ifa Wa Kayejo Mp3 Download

Dami Drizzy, the gifted artist and lyricist is back with another sensational track titled “Ifa Wa Kayejo

Dami Drizzy effortlessly connects with his fans through the power of music. With “Ifa Wa Kayejo” he takes his artistry to new heights, utilizing all available resources to create a profound and captivating musical experience. Get ready to embark on a journey as Dami Drizzy delivers a song that speaks volumes and resonates with his dedicated fanbase.

Ifa Wa Kayejo song by Dami Drizzy is accessible here on Daveplay for free and quick download; appreciate underneath and continue to visit for the Latest Naija Music update.

Listen and Download Dami Drizzy – Ifa Wa Kayejo Mp3 320kbps below:

DOWNLOAD MP3

 

Ifa Wa Kayejo Lyrics by Dami Drizzy

(Yoruba Language)

Mo mo
Ah ah ah ahhh (xcluso, the sound maker)
Eh eh ehhh
Motun ti de gege bi mo se n de
Mo ti be olodumare ki baba ba mi se
Mo lo irinajo,vawon ota won o fe ki n de
Sugbon ifa olokun baba ti ba mi se
Mo mo pe orin ti mo fe ko yii
Won ma gb’ogun

Sugbon eni logo, ko le salailogun
Eni n lo lasan won mu okuta gan won tun so fun
Mo mo pe ifa a ba mi segun
Bi erin ba ji erin a ki olu’gbo
Bi efon ba’ji efon a ki olu odan
Erin to ba ji ti ko ba k’olu’gbo
Beeni efon to ba ji ti ko ba k’olu odan
Awon mejeji won fi ara won fi kasa
Mi ba tija wa beeni mi ba tere wa
Ti won ba ni isoro awa naa na ma saba
Awon to n fi oruko mii (miran) gba yin le gan won ni ifa
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi’ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan

Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi’ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan

Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso
Ebe ni mo be apari inu mi
Ko ma se je ki n rogun elenini
Ki awon kan ko ma se je ipin mi
Ki omo araye ki won ma se damu mi
Ire ni ki n ma ri, baba ma je n ri ibi
Oju to ma ri ire ko le se alai ri ibi
Ti won ba wa fi ifa buru baba ma je won o ri mi
Baba gbo adura mi ko to su mi
Ope fun olorun oo, oba toto
Iyin ye e o, odumare
Ogo ye oo orunmila
Iyin ye oo asiwaju rere
Ifa ti n gba aye lo, ogberi o mo
Bi’ro ba lo fun ogun odun
Ooto ma ba lojo kan

Ifa tide
Ifa wa kayejo
E ma je ka tako ara wa pelu oro siso
Ope fun olorun oo, oba toto (xcluso the sound maker)
Iyin ye e o, odumare
Ogo ye oo orunmila
Iyin ye oo asiwaju rere

ALSO DOWNLOAD 👇👇👇

Upload Your Song


Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.


*